News

Èdè wa ni: Ìkálẹ̀ ni àwọn òbí mi máa ń bá mi sọ nílé, gẹ̀ẹ́sì kọ́- Démiládé Agbédègbẹyọ̀


A bá ọmọdébìnrin Démiládé Agbédègbẹyọ̀ sọ̀rọ̀ lórí bí ó ṣe gbọ́ ẹ̀ka èdè Ìkálẹ̀ tó bẹ́ẹ̀. Ó sì ṣàlàyé pé ẹ̀ka èdè Ìkálẹ̀ ọ̀hún ni àwọn òbí rẹ̀ máa ń bá a sọ nílé lọ́pọ̀ ìgbà ló jẹ́ kó mọ́ ọn lẹ́nu.

A bá àwọn òbí rẹ̀ náà sọ̀rọ̀, wọ́n sì sọ bí ọmọ náà ṣe jẹ́ àkàndá ọmọ, tó sì ń yára há ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan.

  • Breaking News!!! Nigerians can now earn US Dollars legitimately. Participate in the Premium Domain Name business; the profit margin is mind-blowing. Click here to start.

  • Leave a Reply

    Your email address will not be published.

    Back to top button